Àìsáyà 66:18 BMY

18 “Àti Èmi, nítorí ìgbéṣẹ̀ wọn àti èrò wọn, èmi ti múra tán láti wá kó àwọn òrílẹ̀ èdè àti ahọ́n jọ, wọn yóò sì wá wo ògo mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:18 ni o tọ