Àìsáyà 7:13 BMY

13 Lẹ́yìn náà Àìṣáyà sọ pé, “Gbọ́ ní ìsinsìnyí, ìwọ ilé Dáfídì, kò ha tọ́ láti tan ènìyàn ní ṣùúrù, o ó ha tan Ọlọ́run ní ṣùúrù bí?

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:13 ni o tọ