Àìsáyà 7:20 BMY

20 Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò lo abẹfẹ́lẹ́ tí a yá láti ìkọjá odò, ọba Ásíríà, láti fá irun orí àti ti àwọn ẹsẹ̀ẹ yín, àti láti mú irùngbọ̀n yín kúrò pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:20 ni o tọ