Àìsáyà 7:24 BMY

24 Àwọn ènìyàn yóò máa lọ ṣíbẹ̀ pẹ̀lú ọrun àti ọfà nítorí pé ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n ni yóò bo gbogbo ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 7

Wo Àìsáyà 7:24 ni o tọ