Àìsáyà 8:18 BMY

18 Èmi nìyí, àti àwọn ọmọ tí Olúwa fi fún mi. Àwa jẹ́ àmì àti àpẹẹrẹ ní Ísírẹ́lì láti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ẹni tí ó ń gbé ní òké Síhónì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 8

Wo Àìsáyà 8:18 ni o tọ