Àìsáyà 8:20 BMY

20 Sí òfin àti májẹ̀mú! Bí wọn kò bá sọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ yìí, wọn kò ní ìmọ́lẹ̀ ọjọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 8

Wo Àìsáyà 8:20 ni o tọ