Àìsáyà 8:22 BMY

22 Nígbà náà ni wọn yóò síjú wolẹ̀, wọn yóò sì rí ìpọ́njú, òkùnkùn àti ìpòrúúrù tí ó bani lẹ́rù, a ó sì sọ wọ́n sínú òkùnkùn biribiri.

Ka pipe ipin Àìsáyà 8

Wo Àìsáyà 8:22 ni o tọ