Àìsáyà 8:7 BMY

7 fún ìdí èyí, Olúwa fẹ́ mú wá sóríi wọnagbára ìkún omi odòọba Ásíríà àti ògo rẹ̀yóò sì bo gbogbo àyasíi rẹ̀gbogbo bèbè di bíbò mọ́lẹ̀

Ka pipe ipin Àìsáyà 8

Wo Àìsáyà 8:7 ni o tọ