Àìsáyà 9:19 BMY

19 Nípaṣẹ̀ ìbínú Olúwa àwọn ọmọ-ogunilẹ̀ náà yóò di gbígbẹàwọn ènìyàn yóò sì di ohun ìdáná,ẹnìkan kì yóò sì dá arákùnrin rẹ̀ sí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:19 ni o tọ