Àìsáyà 9:21 BMY

21 Mánásè yóò máa jẹ Éfáímù, nígbà tí Éfáímù yóò jẹ Mánásèwọn yóò parapọ̀ dojúkọ Júdà.Ṣíbẹ̀síbẹ̀, ìbínú un rẹ̀ kò yí kúròỌwọ́ọ rẹ̀ sì wà ní gbígbéró.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:21 ni o tọ