Àìsáyà 9:3 BMY

3 Ìwọ ti sọ orílẹ̀-èdè di ńlá;wọ́n sì yọ̀ níwájúu rẹgẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn ti í yọ ayọ̀ ìkóórè,gẹ́gẹ́ bí ènìyàn ti í yọ̀nígbà tí à ń pín ìkógun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:3 ni o tọ