Àìsáyà 9:6 BMY

6 Nítorí a bí ọmọ kan fún wa,a fi ọmọkùnrin kan fún wa,ìjọba yóò sì wà ní èjìkáa rẹ̀.A ó sì má a pè é ní: ÌyanuOlùdámọ̀ràn, Ọlọ́run AlágbáraBaba ayérayé, Ọmọ ọba aládé Àlàáfíà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:6 ni o tọ