Àìsáyà 11:13 BMY

13 Owú jíjẹ Éfáímù yóò pòórá,àwọn ọ̀tá Júdà ni a ó ké kúrò,Éfáímù kò ní jowúu Júdà,tàbí Júdà kó dojú kọ Éfáímù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 11

Wo Àìsáyà 11:13 ni o tọ