Àìsáyà 11:7 BMY

7 Màlúù àti béárì yóò máa jẹun pọ̀,àwọn ọmọ wọn yóò dùbúlẹ̀ pọ̀,kìnnìún yóò sì máa jẹ koríkogẹ́gẹ́ bí akọ màlúù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 11

Wo Àìsáyà 11:7 ni o tọ