Àìsáyà 19:18 BMY

18 Ní ọjọ́ náà ìlú márùn ún ní ilẹ̀ Éjíbítì yóò sọ èdè àwọn ará Kénánì, wọn yóò sì búra àtìlẹyìn fún Olúwa àwọn ọmọ-ogun. Ọ̀kan nínú wọn ni a ó sì máa pè ní ìlú ìparun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:18 ni o tọ