Àìsáyà 19:19 BMY

19 Ní ọjọ́ náà pẹpẹ kan yóò wà fún Olúwa ní àárin gbùngbùn Éjíbítì, àti ọ̀wọ̀n kan fún Olúwa ní etí bodè rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:19 ni o tọ