Àìsáyà 24:23 BMY

23 A ó rẹ òṣùpá sílẹ̀, ojú yóò sì ti òòrùn;nítorí Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò jọbaní orí òkè Ṣíhónì àti ní Jérúsálẹ́mù,àti níwájú àwọn alàgbà rẹ ní ògo.

Ka pipe ipin Àìsáyà 24

Wo Àìsáyà 24:23 ni o tọ