Àìsáyà 25:1 BMY

1 Olúwa, ìwọ ni Ọlọ́run un mi;Èmi yóò gbé ọ ga èmi ó sìfi ìyìn fún orúkọọ̀ rẹnítorí nínú òtítọ́ aláìlẹ́gbẹ́o ti ṣe ohun ńlá,àwọn ohun tí o ti gbèròo rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:1 ni o tọ