Àìsáyà 25:2 BMY

2 Ìwọ ti sọ ìlú di àkójọ àlàpà,ìlú olódi ti di ààtàn,ìlú olódi fún àwọn àjèjì ni kò sí mọ́;a kì yóò tún un kọ́ mọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:2 ni o tọ