Àìsáyà 26:11 BMY

11 Olúwa, ti gbé ọwọ́ọ rẹ̀ sókèṣùgbọ́n àwọn kò rí i.Jẹ́ kí wọ́n rí ìtara rẹ fún àwọn ènìyàn rẹkí ojú kí ó tì wọ́n;jẹ́ kí iná tí a fi pamọ́ fún àwọnọ̀ta rẹ jó wọn run.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26

Wo Àìsáyà 26:11 ni o tọ