Àìsáyà 26:12 BMY

12 Olúwa, ìwọ fi àlàáfíà lélẹ̀ fún wa;ohun gbogbo tí a ti ṣe yọrí ìwọ nió ṣe é fún wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26

Wo Àìsáyà 26:12 ni o tọ