Àìsáyà 26:13 BMY

13 Olúwa Ọlọ́run wa, àwọn olúwa mìírànlẹ́yìn rẹ ti jọba lé wa lórí,ṣùgbọ́n orúkọọ̀ rẹ nìkan ni àwa fi ọ̀wọ̀ fún.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26

Wo Àìsáyà 26:13 ni o tọ