Àìsáyà 27:12 BMY

12 Ní ọjọ́ náà Olúwa yóò sì kó ooré láti ìṣàn omi Éúfírétì wá títí dé Wádì ti Éjíbítì, àti ìwọ, ìwọ ọmọ Ísírẹ́lì, ni a ó kójọ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Àìsáyà 27

Wo Àìsáyà 27:12 ni o tọ