Àìsáyà 27:13 BMY

13 Àti ní ọjọ́ náà, a ó fun fèrè ńlá kan. Gbogbo àwọn tí ń ṣègbé lọ ní Ásíríà àti àwọn tí ń ṣe àtìpó ní Éjíbítì yóò wá sin Olúwa ní òkè mímọ́ ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 27

Wo Àìsáyà 27:13 ni o tọ