Àìsáyà 28:1 BMY

1 Ègbé ni fún òdòdó-ẹ̀yẹ náà, tí í ṣeìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Éfáímù,àti sí òdòdó náà tí ń rọ, tí í ṣeògo ẹwàa rẹ̀,tí ó tò sí orí àfonífojì ẹlẹ́tù lójúàti sí ìlú náà ìgbéraga àwọn tía rẹ̀ sílẹ̀ láti ọ̀dọ̀ wáìnì!

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:1 ni o tọ