Àìsáyà 30:6 BMY

6 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ sí àwọn ẹranko tí ó wà ní Gúúsù:Láàrin ilẹ̀ ìnira àti ìpọ́njú,ti kìnnìún àti abo kìnnìúnti pamọ́lẹ̀ àti ejò olóró,àwọn ikọ̀ náà kó ẹrù àti ọrọ̀wọn lẹ́yìn àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,àwọn ohun ìní wọn ní orí iké àwọn ràkunmí,sí orílẹ̀ èdè aláìlérè,

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:6 ni o tọ