Àìsáyà 31:1 BMY

1 Ègbé ni fún àwọn tí ó ṣọ̀kalẹ̀ lọ síÉjíbítì fún ìrànwọ́,tí wọn gbẹ́kẹ̀lée eṣintí wọ́n fi ìgbẹ́kẹ̀lé wọn sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ kẹ̀kẹ́ ẹṣin wọnàti agbára ńlá àwọn ẹlẹ́ṣin wọn,ṣùgbọ́n ti wọn kò bojúwo Ẹni-Mímọ́ Ísírẹ́lì n nì,tàbí kí wọn wá ìrànlọ́wọ́ lọ́dọ̀ Olúwa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 31

Wo Àìsáyà 31:1 ni o tọ