Àìsáyà 31:2 BMY

2 Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ òun pẹ̀lú jẹ́ ọlọgbọ́n ó sì lè mú ìparun wá;òun kì í kó ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ.Òun yóò dìde sí ilé àwọn ìkà,àti sí àwọn tí ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún aṣebi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 31

Wo Àìsáyà 31:2 ni o tọ