Àìsáyà 31:3 BMY

3 Ṣùgbọ́n ènìyàn ṣáà ni àwọn ará Éjíbítìwọn kì í ṣe Ọlọ́run;ẹran ara ni àwọn ẹṣin wọn, kì í ṣe ẹ̀mí.Nígbà tí Olúwa bá na ọwọ́ọ rẹ̀ jáde,ẹni náà tí ó ń ṣèrànwọ́ yóò kọṣẹ̀,ẹni náà tí à ń ràn lọ́wọ́ yóò ṣubú;àwọn méjèèjì yóò sì jùmọ̀ parun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 31

Wo Àìsáyà 31:3 ni o tọ