Àìsáyà 36:1 BMY

1 Ní ọdún kẹrìnlá ìjọba Heṣekáyà, Ṣenakérúbù ọba Áṣíríà kọlu gbogbo àwọn ìlú olódi ní ilẹ̀ Júdà ó sì kó gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:1 ni o tọ