Àìsáyà 36:17 BMY

17 títí tí èmi yóò fi mú un yín lọ sí ilẹ̀ kan tí ó dàbí i ti yín, ilẹ̀ tí ó ní irúgbìn oníhóró àti wáìnì tuntun, ilẹ̀ tí ó ní àkàrà àti ọgbà àjàrà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:17 ni o tọ