Àìsáyà 41:17 BMY

17 “Àwọn talákà àti aláìní wá omi,ṣùgbọ́n kò sí;ahọ́n wọn ṣáàápá fún òrùngbẹ.Ṣùgbọ́n Èmi Olúwa yóò dá wọn lóhùn;Èmi, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kì yóò kọ̀ wọ́n sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:17 ni o tọ