Àìsáyà 41:18 BMY

18 Èmi yóò mú kí odò kí ó sàn ní àwọnibi gíga pọ́nyán ún,àti oríṣun omi ní àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀.Èmi yóò sọ aṣálẹ̀ di adágún omi,àti ilẹ̀ tí ó ṣáàápá yóò di orísun omi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:18 ni o tọ