Àìsáyà 41:19 BMY

19 Èmi yóò fi sínú aṣálẹ̀igi kédárì àti akaṣíà, mítílì àti ólífì.Èmi yóò da páínì sí inú ilẹ̀ síṣá,igi fíri àti ṣípírẹ́ṣì papọ̀

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:19 ni o tọ