Àìsáyà 41:20 BMY

20 tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ènìyàn yóò fi rí i tí wọn yóò sì fi mọ̀,kí wọn ṣàkíyèsí kí ó sì yé wọn,pé ọwọ́ Olúwa ni ó ti ṣe èyí,àti pé Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ni ó ti dá èyí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:20 ni o tọ