Àìsáyà 41:22 BMY

22 “Mú àwọn ère-òrìṣà rẹ wọlé láti sọ fún waohun tí yóò ṣẹlẹ̀.Sọ fún wa ohun tí àwọn nǹkan àtijọ́ jẹ́,kí àwa lè ṣe àgbéyẹ̀wò wọnkí àwa sì mọ àbájáde wọn níparí.Tàbí kí o sọ fún wa ohun tí ó ń bọ̀ wá,

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:22 ni o tọ