Àìsáyà 41:23 BMY

23 ẹ sọ fún wa ohun ti ọjọ́ iwájú mú dáníkí àwa kí ó lè mọ̀ pé Ọlọ́run niyín.Ẹ ṣe nǹkankan, ìbáà ṣe rere tàbí búburú,tó bẹ́ẹ̀ tí àyà yóò fi fò wá tí ẹ̀rù yóò sì fi kún inú wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:23 ni o tọ