Àìsáyà 42:13 BMY

13 Olúwa yóò rìn jáde gẹ́gẹ́ bí i ọkùnrin alágbára,gẹ́gẹ́ bí jagunjagun yóò ti gbé ohun ipá rẹ̀ ṣókè;pẹ̀lú ariwo, òun yóò ké igbe ogunòun yóò sì ṣẹ́gun àwọn ọ̀ta rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:13 ni o tọ