Àìsáyà 42:14 BMY

14 “Fún ìgbà pípẹ́ ni mo ti dákẹ́ jẹ́ẹ́,mo ti wà ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, mo sì kó ara ró.Ṣùgbọ́n ní àkókò yìí, gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó ń rọbí,mo ṣunkún, mo sì ń mí hẹlẹ hẹlẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:14 ni o tọ