Àìsáyà 43:5 BMY

5 Má bẹ̀rù nítorí èmi wà pẹ̀lúù rẹ;Èmi yóò mú àwọn ọmọ rẹ láti ìlà oòrùn wáèmi ó sì kó ọ jọ láti ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 43

Wo Àìsáyà 43:5 ni o tọ