Àìsáyà 44:22 BMY

22 Èmi ti gbá gbogbo ìkùnà rẹ dànù bí i kùrukùru,àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ bí ìrì òwúrọ̀.Padà sọ́dọ̀ mi,nítorí mo ti rà ọ́ padà.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:22 ni o tọ