Àìsáyà 44:23 BMY

23 Kọrin fáyọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, nítorí Olúwa ló ti ṣe èyí;kígbe ṣókè, Ìwọ ilẹ̀ ayé níṣàlẹ̀.Bú sí orin, ẹ̀yin òkè ńlá,ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín,nítorí Olúwa ti ra Jákọ́bù padà,ó ti fi ògo rẹ̀ hàn ní Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:23 ni o tọ