Àìsáyà 44:24 BMY

24 “Ohun tí Olúwa wí nìyìíOlùràpadà rẹ tí ó mọ ọ́láti inú ìyá rẹ wá:“Èmi ni Olúwatí ó ti ṣe ohun gbogbotí òun nìkan ti na àwọn ọ̀runtí o sì tẹ́ ayé pẹrẹṣẹ òun tìkálára rẹ̀,

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:24 ni o tọ