Àìsáyà 44:9 BMY

9 Gbogbo àwọn tí ń gbẹ́ ère jásí asán,àti àwọn ohun tí wọn ń kó pamọ́kò jámọ́ nǹkankan.Àwọn tí yóò sọ̀rọ̀ fún wọn fọ́ lójú;wọ́n jẹ́ aláìmọ́kan sí ìtìjú ara wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:9 ni o tọ