Àìsáyà 45:21 BMY

21 Jẹ́ kí a mọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀, fihàn wájẹ́ kí wọn jọ dámọ̀ràn papọ̀.Ta ló ti sọ èyí lọ́jọ́ tí o ti pẹ́,ta ló ti wí èyí láti àtètèkọ́ṣe?Kì í ha á ṣe Èmi, Olúwa?Àti pé kò sí Ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn mi,Ọlọ́run olódodo àti olùgbàlà;kò sí ẹlòmìíràn àfi èmi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:21 ni o tọ