Àìsáyà 45:22 BMY

22 “Yípadà sí mi kí a sì gbà ọ́ là,ẹ̀yin ìpẹ̀kun ilẹ̀-ayé;nítorí Èmi ni Ọlọ́run kò sì sí ẹlòmìíràn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:22 ni o tọ