Àìsáyà 46:13 BMY

13 Èmi ń mú òdodo mi bọ̀ nítòsí,kò tilẹ̀ jìnnà rárá;àti ìgbàlà mi ni a kì yóò dádúró.Èmi yóò fún Ṣíhónì ní ìgbàlàògo mi fún Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 46

Wo Àìsáyà 46:13 ni o tọ