Àìsáyà 47:1 BMY

1 “Ṣọ̀kalẹ̀, jókòó nínú eruku,wúndíá ọmọbìnrin Bábílónì;jókòó ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀ láìsí ìtẹ́,ọmọbìnrin àwọn ará Bábílónì.A kì yóò pè ọ́ ní aláìlókun àti ẹlẹgẹ́ mọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 47

Wo Àìsáyà 47:1 ni o tọ