Àìsáyà 49:2 BMY

2 Ó ṣe ẹnu mi bí idà tí a pọ́n,ní abẹ́ òjìji ọwọ́ rẹ̀ ni ó ti pamí mọ́:ó ṣe mí ní ọfà tí a ti dán,ó sì fi mí pamọ́ sínú àpó rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:2 ni o tọ