Àìsáyà 49:3 BMY

3 Ó sọ fún mi pé, “Ìránṣẹ́ mi ni ìwọ í ṣe,Ísírẹ́lì nínú ẹni tí n ó ti fi ògo mi hàn.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:3 ni o tọ